Total Pageviews

Welcome

Welcome, welcome! and thanks for stopping by!
You're gonna love me
But if you don't...
see that red X at the top of the page?
The right side...
yep, that one, it's impossible to miss...
Click.

Pages

Wednesday, October 21, 2009

yoruba post! eyin aniyan miiiiii


eyin eniyan miiiii.... bawo ni?? mi o ma mo idi ti mo fi n so yoruba loni ooo,

sugbon, eni wa different... hehe, she mi o le so yoruba la i fi english si ni???

ok, o ti dara... ehmmm, ki ni mo fe so na?? mo ti gbagbe sha...iya mi pe mi loni, won fi owo ranse si mi! inu mi dun to je pe!!! bata ni ma fi ra...bata ati aso...

mo ti gba yara tuntun!!! mo de ni roommate tuntun...ki ni yoruba fun roommate gan?? ehm *o bi roommate re* ehen, omo-yara. oruko re n je miss x...very nice person de ni...

anyway...emi nlo oh, mo ni physiology ni ola...mio de tii ka anything!
gbogbo everybody lo ti fe mo blog mi yii,mi ode ni gba fun won, iro lon pa...maa kan fun won ni blog post elo miran lati ka ni, nothing do me hehe...

mo ma delete awon kan lati ori fb mi, won ti ma n be ju! won de ma n bi mi ninu...so mo ma delete at least 200 ninu won...jowo, ti mo ba delete re, ma binu si mi ni, mo nife re pupo, sugbon, o ti bere lati ma bi mi ninu...

ki ni ti awon freshers yi gan?? won fe ma toast emi senior won! se won fori gbagi ni?? hmmn,oju mi ma n ri o!

sooo, emi ti soro tan ni yen, mo n lo se ise ti awon parents mi ran mi wa se...IWE KIKA!

awon agba wa ni, ''ti mo ba kawe mi, bata mi a dun ko-ko-ka'' hehe...

p.s : eyin ti post yii o ye, ema binu ooo, o kan wu mi lati so ede loni ni o!!!

pps: e ma si binu wipe blog post yii wa random... idunnu lofa! (mo hope pe idunnu mean happiness??)

mo luff gbogbo yin ohhh,

odabo.

_xx11 CerebrallyEndowed views:

Anonymous said...

mo like post yi gan ni oh..oti wun mi lati ko post ni yoruba but mi o fe lo confuse awon ppl me..lol.

Ahh awon ti won fe mo blog emi na po oh..awon nosy ppl..hehe. Ka iwe re dada oh!! :)

CerebrallyBusy said...

o seun jere ore! ko post re jo, awon to ba fe confuse......mmm, mi o soro ohhhh

Azazel said...

Kilode?
Ba wo ni but translation fit dey here?

iphyigbogurl said...

i like people like u who can speak their language jare.
ngwa kilo n translation ni?
N ko understand post yi.
se o gbo?
eshe pupo.....lol

CerebrallyBusy said...

azazel: lol i go try sogbo??

iphy: heheeeee lolll gurl u crack me up lolll, mo ti gbo o!

Myne Whitman said...

Ba wo ni, ki lon shele?

blogoratti said...

Ki ni big deal...lol.

Princess X said...

Iru post wo gan le leyi? O mu inu mi dun gba! Ma rep lo o...
x

CerebrallyBusy said...

myne: mo wa pa lol

blogoratti: ko si big deal rara o!

princess x: eshe o jere ore :))

tunrayo said...

o ma try gan o. mi le ko yoruba to yi.

neefemi said...

hahah mo feran post yi gan - inu mi dun lati ri pe awon omo insi le ko ede won - kilode ti mi o le follow e lori blogger o, ose fun birthday msg lori blog mi - ko take care